Luke 9:1

Jesu rán ọmọ-ẹ̀yìn méjìlá lọ wàásù

1 aÓ sì pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ méjìlá jọ, ó sì fún wọn ní agbára àti àṣẹ lórí àwọn ẹ̀mí èṣù gbogbo, àti láti wo ààrùn sàn.
Copyright information for YorBMYO